SONG LYRICS:
Enitaye ropè kole pagò
To pada, to pada kole nla fun baba
Enitan só wipe kole deniyan
Topada wa deni aji tan nò wo faraye
Mosínmí le ò baba mi mo sin mi
Moyòn fanda ló dò re mosin mi
Mosin mi le ö baba mi mosinmi
Emi ma ti sinmi le ò
Sinmi le ò
Hallelujah mori iye gba
Ni ni Oluwa
Hallelujah mo ri yegba nipa eje òdó agun tan (x2)
Enitaye ropè kole pagò
To pada, to pada kole nla fun baba
Enitan só wipe kole deniyan
Topada wa deni aji tan nò wo faraye
Mosínmí le ò baba mi mo sin mi
Moyòn fanda ló dò re mosin mi
Mosin mi le ö baba mi mosinmi
Emi ma ti sinmi le ò
Sinmi le ò